Jùmọ̀kẹ́ Ọdẹ́tọ́lá

Ọlájùmọ̀lẹ́ Ọdẹ́tọ́lá (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lédè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n ní kété tó dára pọ̀ mọ́ tí èdè Yorùbá ní ìràwọ̀ rẹ̀ tàn.[2]

Ọlájùmọ̀lẹ́ Ọdẹ́tọ́lá
Ọjọ́ìbíOctober 16
Iléẹ̀kọ́ gígaAjayi Crowther University
Iṣẹ́Filmmaker

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Jùmọ̀kẹ́ kàwé gírámà rẹ̀ ní Abẹ́òkúta Grammar School. Ó kàwé gboyè dìgírì rẹ̀ ní ifáfitì tí Ajayi Crowther University, níbi tí ó ti gbà ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìfitétí àti ìbánisọ̀rọ̀ nípa lílo ẹ̀rọ ìgbàlódé, kọ̀m̀pútà, lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Federal University of Agriculture, Abẹ́òkúta, níbi tí ó ti kàwé gboyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ ìjìnlè kọ̀m̀pútà.[3]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Bada, Gbenga. "Boyfriends are distractions,' AMVCA's best indigenous act says". Pulse. Archived from the original on 2019-12-21. Retrieved 2018-04-08. 
  2. "7 THINGS YOU PROBABLY DIDN’T KNOW ABOUT TALENTED ACTRESS, JUMOKE ODETOLA". Information Nigeria. January 24, 2018. Retrieved 2018-04-08. 
  3. 3.0 3.1 3.2 Tofarati, Ige (January 28, 2018). "I can only act romantic roles with professionals– Jumoke Odetola". Punch. Retrieved 2018-04-08. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named vanguardcoverage
  5. 5.0 5.1 5.2 5.3 5.4 5.5 5.6 5.7 "Meet JUMOKE ODETOLA NEW NOLLYWOOD’S DELIGHT". BON Magazine. August 13, 2015. Archived from the original on 2019-12-21. Retrieved 2018-04-08. 
  6. "Kanipe Full Cast and Crew". NList. January 1, 2017. Retrieved 2019-08-23. 
  7. "After Successful Lagos Screening, New Flick, Wetin Women Want, Goes To Kwara". Eagle online. February 7, 2018. Retrieved 2018-04-08.