Jacob Bernoulli tí a mọ̀ bákan náà sí James tàbí Jacques (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1654, tí ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1705) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Switzerland àti ọ̀kan lára àwọn onímọ̀ Ìṣirò pàtàkì tó pọ̀ nínú ẹbí Bernoulli.[1][2]

Jacob Bernoulli
Jacob Bernoulli
Ìbí(1654-12-27)27 Oṣù Kejìlá 1654
Basel, Switzerland
Aláìsí16 August 1705(1705-08-16) (ọmọ ọdún 50)
Basel, Switzerland
IbùgbéSwitzerland
Ọmọ orílẹ̀-èdèSwiss
PápáMathematician
Ilé-ẹ̀kọ́University of Basel
Ibi ẹ̀kọ́University of Basel
Doctoral studentsJohann Bernoulli
Jacob Hermann
Nicolaus I Bernoulli
Ó gbajúmọ̀ fúnBernoulli differential equation
Bernoulli numbers
(Bernoulli's formula
Bernoulli polynomials
Bernoulli map)
Bernoulli trial
(Bernoulli process
Bernoulli scheme
Bernoulli operator
Hidden Bernoulli model
Bernoulli sampling
Bernoulli distribution
Bernoulli random variable
Bernoulli's Golden Theorem)
Bernoulli's inequality
Lemniscate of Bernoulli
Religious stanceCalvinist
Notes
Brother of Johann Bernoulli.



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Jacob Bernoulli (1655 - 1705)". MacTutor History of Mathematics. Retrieved 2019-12-16. 
  2. "Bernoulli Brothers - 18th Century Mathematics". The Story of Mathematics. Retrieved 2019-12-16.