Johann Bernoulli (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1667, ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1748)[1] jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Swiss onímọ̀ Ìṣirò àti ọ̀kan nínú àwọn onímọ̀ Ìṣirò pàtàkì nínú ẹbí Bernoulli. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ sí kalkulosi ikerelailopin, ó sì kọ́ Leonhard Euler lẹ́kọ̀ọ́ nígbà èwe rẹ̀.[2]

Johann Bernoulli
Johann Bernoulli
Ìbí(1667-07-27)27 Oṣù Keje 1667
Basel, Switzerland
Aláìsí1 January 1748(1748-01-01) (ọmọ ọdún 80)
Basel, Switzerland
IbùgbéSwitzerland
Ọmọ orílẹ̀-èdèSwiss
PápáMathematician
Ilé-ẹ̀kọ́University of Groningen
University of Basel
Ibi ẹ̀kọ́University of Basel
Doctoral advisorJacob Bernoulli
Doctoral studentsDaniel Bernoulli
Leonhard Euler
Johann Samuel König
Pierre Louis Maupertuis
Ó gbajúmọ̀ fúnDevelopment of infinitesimal calculus
Catenary solution
Bernoulli's rule
Bernoulli's identity
Religious stanceCalvinist
Notes
Brother of Jakob Bernoulli, and the father of Daniel Bernoulli.



  1. "Johann Bernoulli (1667 - 1748)". MacTutor History of Mathematics. Retrieved 2019-12-16. 
  2. "Swiss mathematician". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-12-16.