The Jolly Nyame Stadium jẹ́ pápá ìdárayá tí wọ́n lè lò fún oun kóun ní Jalingo, Nàìjíríà. Wọn máa ń sábà lòó fún bọ́ọ̀lù gbígba. Ó sì jẹ́ pápá ìdárayá fún Taraba FC. Wọn kọ́ pápá ìdárayá yìí ní ọdún 2002, o sì lè gba èèyàn bíi 30,000.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Jolly Nyame Stadium". Soccerway. 2012-08-29. Retrieved 2022-01-19. 
  2. Oni, Kolade (2015-10-30). "LMC bans Jolly Nyame Stadium for one year, fines El Kanemi, Maikaba". Goal.com. Retrieved 2022-01-19.