James Manager
Olóṣèlú
James Manager jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Delta ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2003 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
James Manager | |
---|---|
Alága ẹ̀ka People's Democratic Party ti ìpị́nlẹ̀ Delta | |
In office ọdún 1998 – ọdún 1999 | |
Arọ́pò | Pius Sinebe |
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga ọdún 2007 | |
Constituency | Gúúsù Delta |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oṣù Keje 1960 (ọmọ ọdún 64) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Profession | Olóṣèlú |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Senate Raises Panel Over Military Action". Daily Independent (Lagos). 21 May 2009. Retrieved 2009-09-15.
- ↑ "War in the Creeks of Nigeria - Stop This Carnage, Say Niger Delta Leaders". Somali Press. May 18, 2009. Archived from the original on 2012-02-16. Retrieved 2009-09-15.
- ↑ "Any Nigerian can be N-Delta minister - Senator". The Nigerian Observer. September 15, 2009. Retrieved 2009-09-15.