James Mancham
Sir James Richard Marie Mancham KBE (ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹjọ ọdún 1939 – ọjọ́ kẹjọ oṣù Kínní ọdún 2017) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó dá ẹgbẹ́ òṣèlú Seychelles Democratic Party kalẹ̀, òun ni ó jẹ́ Ààrẹ Seychelles láti ọdún 1976 di ọdún 1977.
James Mancham | |
---|---|
Official portrait, 1976 | |
1st President of Seychelles | |
In office 29 June 1976 – 5 June 1977 | |
Alákóso Àgbà | France-Albert René |
Asíwájú | Office established |
Arọ́pò | France-Albert René |
1st Prime Minister of Seychelles | |
In office 1 October 1975 – 28 June 1976 | |
Asíwájú | Office established |
Arọ́pò | France-Albert René |
Chief Minister of the Crown Colony of Seychelles | |
In office 12 November 1970 – 1 October 1975 | |
Asíwájú | Office established |
Arọ́pò | Office abolished |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | James Richard Marie Mancham 11 Oṣù Kẹjọ 1939 Victoria, British Seychelles |
Aláìsí | 8 January 2017 Glacis, Seychelles | (ọmọ ọdún 77)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Seychelles Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 3 |
Profession | Lawyer Politician Writer |
Nípa ayé àti ikú rẹ̀
àtúnṣeA bí Mancham sínú ìdílé ọlọ́rọ̀, òun ni ọmọkùnrin àkọ́kọ́ Richard àti Evelyn Mancham. Bàbá rẹ̀ ọmọ orílẹ̀ ède China, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède Fùrànsé.[1]
Ó fẹ́ Heather Jean Evans ní ọdún 1963, wọ́n sì bí ọmọbìnrin kan tí wọ́n sọ ní Caroline àti ọmọkùnrin kan tí wọ́n sọ ní Richard, ìgbéyàwó wọn tú ká ní ọdún 1974.[2] In 1985, he married Australian journalist Catherine Olsen and had one son named Alexander.[3]
Mancham kú ikú òjìji ní ọjọ́ kẹjọ oṣù Kínní ọdún 2017, ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta nígbà tí ó fi ayé sílẹ̀.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Obituary: Sir James Mancham, deposed playboy president of Indian Ocean 'islands of love'
- ↑ "Passing away of former President Sir James Mancham (KBE) - Archive - Seychelles Nation". Seychelles Nation. http://www.nation.sc/archive/252542/passing-away-of-former-president-sir-james-mancham-kbe.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ Vannier, Rassin; Bonnelame, Betymie (8 January 2017). "Former Seychelles' president James Mancham dies at residence" (in en). Seychelles News Agency (Victoria, Seychelles). http://www.seychellesnewsagency.com/articles/6572/Former+Seychelles+president+James+Mancham+dies+at+residence.
- ↑ "Seychelles Founding President passed away" (in en). ETN Global Travel Industry News. 8 January 2017. http://www.eturbonews.com/76605/seychelles-founding-president-passed-away.