France-Albert René tí àwọn míràn ń pẹ̀ ní Albert René or F.A. René; (fr; ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1935[1] – ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2019)[2] jẹ́ agbejọ́rò àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó jẹ́ Ààrẹ Seychelles láàrin ọdún 1977 sí 2004, òun ni ààrẹ kejì láti gun orí àléfà ipò Ààrẹ Seychelles. Òun ni ó tún jẹ́ mínísítà àgbà orílẹ̀ ède láàrin ọdún 1976 sí 1977.

France-Albert René
2nd President of Seychelles
In office
5 June 1977 – 14 July 2004
Vice PresidentJames Michel
(1996–2004)
AsíwájúJames Mancham
Arọ́pòJames Michel
2nd Prime Minister of Seychelles
In office
29 June 1976 – 5 June 1977
ÀàrẹJames Mancham
AsíwájúJames Mancham
Arọ́pòPosition abolished
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1935-11-16)16 Oṣù Kọkànlá 1935
Victoria, Colony of Seychelles
Aláìsí27 February 2019(2019-02-27) (ọmọ ọdún 83)
Mahé, Seychelles
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSeychelles People's Progressive Front
(Àwọn) olólùfẹ́Karen Handley (1956)
Geva Adam (1974)
Sarah Zarquani (1992)
Alma materKing's College London
ProfessionLawyer, politician
Signature

Ọ̀pọ̀ òṣìṣẹ́ ìjọba mà ń pè ní inagi jẹ rẹ̀ "the Boss", àwọn míràn sì ma ń pè é ní

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Gabbay, Rony; Ghosh, R. N. (28 February 1992). Economic development in a small island economy: a study of the Seychelles Marketing Board. Academic Press International. ISBN 9780646075501. https://books.google.com/books?id=0n4uAQAAIAAJ&q=France-Albert+Ren%C3%A9+16+November+1935. 
  2. "France Albert Rene, former President of Seychelles, dies at age 83". www.seychellesnewsagency.com.