James Vivian Clinton
James Vivian Clinton, OBE (láti ọjọ́ kẹfà oṣù kejì ọdún 1902 - sí ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1973) jẹ́ Akọ̀ròyìn ọmọ bíbí ìlú Gold Coast ní orílẹ̀-ède Sierra Leone. Ó jé olùgbé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wá láti ìdílé Sierra Leone Creole ni apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè India àti àwọn ọmọ bíbí Europe tí wọ́n ní òmìnira láti lọ sí ibikíbi ní apá ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó padà gbé ní ìlú Calabar ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ OBE in 1949,[1][2][3][4] ó sì ní ìbáṣẹpọ̀ tó dájú pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Sierra Leone
James Vivian Clinton | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 6 February 1902 Axim |
Aláìsí | 18 May 1973 Lagos |
Orílẹ̀-èdè | British subject of Sierra Leone, Sierra Leonean, Nigerian |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Uwechue, Ralph (1991). Makers Of Modern Africa: Profile in History (2nd ed.). United Kingdom: Africa Books Limited. pp. 162–163. ISBN 0903274183.
- ↑ African Print Cultures Network. Meeting (2013 : Birmingham, England) (29 September 2016). African print cultures : newspapers and their publics in the twentieth century. Peterson, Derek R., 1971-, Hunter, Emma, 1980-, Newell, Stephanie, 1968-. Ann Arbor. ISBN 978-0-472-12213-4. OCLC 960701533. https://www.worldcat.org/oclc/960701533.
- ↑ rp441 (2017-07-21). "Downing's Early Black Cantabs". Downing College Cambridge (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-29.
- ↑ Falola, Toyin; Genova, Ann (2009). Historical Dictionary of Nigeria. United Kingdom: The Scare Crow press, Inc.. pp. 95. ISBN 9780810863163.