Janet Febisola Adeyemi
Janet Febisola Adeyemi (ọjọ́ ìbí Jẹ́ oṣù kẹjọ ọdún 1958) jẹ́ ààrẹ tí ó wà ní pò leke fún àwọn obìnrin tí wọn ń ṣiṣẹ́ Mining ní orílé èdè Nàìjíríà àti alàfaramọ́ fún àwọn oníṣe mining ní ilé ókéré. O ṣiṣẹ́ lábẹ́ àwọn ìgbìmò fún Gómìnà tí wọn yàn ní ìpínlè Ondó tí wọn pè ní Strategic Development And policy Implementation ní ọdún 2016. [2] Ò wà lára àwọn ẹgbẹ́ bọ́ọ̀dù fún Civil Society Network Coordination and Interventional nípa tí ìṣẹlẹ tí ó ṣẹlẹ̀ ní ìpínlè Kaduna.[3] Ó tí ṣiṣe takuntakun ní ilé àwọn aṣòfin tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lára àwọn Ọmọ ẹgbẹ ICRC,[4] ó tún jẹ́ Senior Special Assistant sí Ààrẹ níbi ká gbimọ ọ̀rọ̀ ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, Ó jẹ́ alága fún ẹgbẹ́ iṣẹ Kòkó ní ìpínlè Ondó, àti àwọn iṣé mìíràn tí o jẹ́ mọ́ ìlọsíwájú.
Janet F. Adeyemi | |
---|---|
Executive Board Member of Infrastructure Concession Regulatory Commission | |
In office 2013 – 2015[1] | |
Senior Special Assistant to the President on National Assembly Matters | |
In office 2006–2007 | |
Chairman, Cocoa Processing Industry Ondo State | |
In office 2003–2006 | |
National House of Representatives for Ondo State | |
In office May 1999 – May 2003 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Keje 1958 Ondo State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Alma mater | Loughborough University University of Ife |
Occupation | Civil engineer, geologist |
Website | http://www.wimng.org |
Nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ ilé ìgbìmò aṣòfin, ó jẹ́ alága fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Irrigation, Flood and Erosion Control àti ìgba Kejì Alága ẹgbẹ́ Solid Minerals and Water Resources. Ó jẹ́ onígbọ̀wọ́ fún àwọn ohùn tí ó bá òfin mu lára, nígbà náà ní ó ń ṣe ìṣe fún àwọn ẹgbẹ òṣèlú kékèké. Ní oṣù kẹsán ní ọdún 2018, o pinu láti gbé ìgbà fún ipò Sẹ́nátọ̀ ní ìpínlè Ondó lábẹ ẹgbẹ òṣèlú All Progressive Congress (APC).
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé àti àwọn ẹbí rẹ̀
àtúnṣeJanet Adéyẹmí jẹ́ ọmọ bíbí Olóyè Ebenezer Akínbọ̀boyè Adépọ̀jù àti Olóye Àgbà ọmọọba Florence Mọ́tinọlá Adépọ̀jù tí wọ́n pè ní Yagbata ti Ilé Olúji ní ìpínlè Ondó. Bàbá rẹ̀, Olóyè Adépọ̀jù jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba tí ó ń ṣe àyẹwò lori àwọn tí wón ń ṣiṣe lori òpópó-ònà tí ó wọnú Ilé Olúji. Nígbà tí ìyáà rẹ ti ó jẹ Olóyè àgbà jẹ́ onísòwò tí ó yanrantí tí ó jáde láti ìdílè kàn tí ó dáńtọ́, nípasẹ èyí ni ó fí dì onísòwò tí ayé mọ ní ìlú rẹ̀. Lára àwọn mọ́lẹ́bí rẹ̀, Ọba(Engr.) Stephen Súláé Adédùgbẹ̀ jẹ́ ọba tí ó wàjà ní ilé Olúji tí ó jẹ́ ẹni kàn ti ó nípa gbóògì ní gbogbo ile Kaaro-o-jiire orílé èdè Nàìjíríà,[5] the Jegun of Ile-Oluji.
Ó dàgbà ní ìpínlè Jọ́ọ̀sì nígbà oògùn kàn gbogbo awọn àwọn mọ́lẹbí rẹ fẹ pàdánù èmi wọn tan nígbà náà, Sùgbọ́n ará-ile rẹ̀ kan ní ó ṣe ọnà àti sá kúrò nínú ìpínlè náà wásí ìlú tí wøn bi sí.
Adéyemí kàwé ní Fásiti Ọbáfẹmi Awólọ́wọ̀ ní ilé ifè láti gbọyè nínú ẹ̀kọ́ Geology. Nígbà tí ó kàwé tán, ó sin ìjọba gégé bí akẹ́kọ̀ọ́ Geology. Òun àti ọkọ rẹ̀ (Engr. T.A.T Adéyemí) jẹ́ àwọn tí wọn gbà ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ láti ọwọ́ Egbe Commonwealth and European Economic Commission láti lọ kàwé ní Fásiti |Loughborough of Technology ni UK.
Awọn àmì ẹ̀yẹ
àtúnṣeNípa mímọ rírí àwọn ohùn tí ó tí gbé ṣe ní òkè òkun àti ní orílé èdè Nàìjíríà, o gbà awọn ohun wọnyi:
- National Delegate at 2017 United Nation Commission on the Status of Women
- Fellow of Nigerian Mining and Geosciences Society
- Political Achievers Award, organized by Movement for Political Awareness and Mass Emancipation
- Outstanding Female Legislative Award, organized by National Council for Women Society
- PSN Gold Award for best Female Legislator
- Inner-Wheel Merit Award for Selfless Service to Womanhood and the Nation
- Merit Award by Cocoa Association of Nigeria
- Nigerian Women’s Pride Merit Award by Niger Wives Association of Australia
- Prime International Corporate Development in Nigeria Merit 2002 Award
- Merit Award by the Nigerian Association of Geosciences and Mining Students UNIJOS & FUTA Chapters
- Female Parliamentarian Award for Africa – CAFS 5th Anniversary 2002
- Rare Gems 2002 Award, organized by UNFPA, UNIFEM & WODEF
- Honorary Doctorate Degree from Columbus International University and West African Merit Award Council on 28 September 2002
- Ile-Oluji National Women of Ile-Oluji students merit Award
- Global Rights Award in recognition of outstanding contribution to women issues
- National Union of Market Women Association Award for outstanding contributor to gender issues 2002
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adeyemi, Janet. "Jfa4senate2019". Facebook. Retrieved 24 September 2018.
- ↑ Ondo State Governor-Elect Aketi Transitional Team (2016-12-29) Inauguration of the Strategic Development and Policy Implementation Committee[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Aketi.org
- ↑ "Utomi, civil society leaders of thought intervene in southern Kaduna crisis". 2017-01-23.
- ↑ http://allafrica.com/stories/201305090644.html. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ Egede, Dorcas (2016-01-10) Monarchs who passed in 2015, The Nation