Jean-Marie Doré (ojoibi 1939?[1]) je oloselu ara orile-ede Guinea. O je Aare egbe oloselu Union for the Progress of Guinea (UPG) ati Alakoso Agba ile Guinea lati January 2010.

Jean-Marie Doré
Prime Minister of Guinea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
26 January 2010
ÀàrẹSékouba Konaté (Acting)
AsíwájúKabiné Komara
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1939
Guinée Forestière, Guinea
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnion for the Progress of Guinea



  1. Saliou Samb, "Possible candidates for Guinean PM job", Reuters, 14 January 2010.