Jean Ping (born November 24, 1942[1][2][3]) je asoju ati oloselu omo orile-ede Gabon to tun je Alaga Igbimo Isokan Afrika.[3][4] O tun ti je teletele Alakoso Oro Okere fun orile-eded Gabon lati 1999 titi de 2008, o si wa nipo Aare Apejo Gbogbogboo Agbajo Sisodokan awon Orile-ede from 2004 to 2005.

Jean Ping speaking at the African Union Summit in Ethiopia, February 2, 2008


ItokasiÀtúnṣe