Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè

Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè
(Àtúnjúwe láti UN)

Àjọ Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè tabi Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ni soki (ní èdè Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye. OA je didasile ni odun 1945 leyin Ogun Agbaye Keji lati sedipo Apejo awon Orile-ede, lati jawo awon ogun larin awon orile-ede, ki o si pese aye fun ijiroro larin won. O ni opolopo eka akojoegbe kekeke lati le se awon ise wonyi.

HeadquartersNew York City (international territory)
Official languages
Type Intergovernmental organization
Ọmọ ẹgbẹ́ 193 member states
2 observer states
Àwọn olórí
 -  Secretary‑General António Guterres
 -  Deputy Secretary-General Amina J. Mohammed
 -  General Assembly President Tijjani Muhammad-Bande
 -  Economic and Social Council President Mona Juul
 -  Security Council President Dang Dinh Quy
Ìdásílẹ̀
 -  UN Charter signed 26 Oṣù Kẹfà 1945; ọdún 74 sẹ́yìn (1945-06-26) 
 -  Charter entered into force 24 Oṣù Kẹ̀wá 1945; ọdún 74 sẹ́yìn (1945-10-24) 
Ibiatakùn
UN.org
UN.int



ItokasiÀtúnṣe

  1. Official Languages Archived 12 July 2015 at the Wayback Machine., www.un.org. Retrieved 22 May 2015.