Jìmí Agbájé
Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Jimi Agbaje)
Olújìmí Kọ́láwọlé Agbájé (tí à ń pè ní Jìmí Agbájé, tí a bí ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 (March 2, 1957), jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ olóògún òyìnbó àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó díje dú ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2015 àti 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́-òṣèlú People's Democratic ṣùgbọ́n ó pàdánù gbogbo rẹ̀. [1][2].
Jimi Agbaje | |
---|---|
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹta 1957 Lagos, Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party (PDP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Abiola Agbaje (née Bankole) (1982–present) |
Alma mater | St Gregory's College, Lagos University of Ife (now Obafemi Awolowo University) |
Occupation | Pharmacist, Politician |
Website | jimiagbaje.com |
Nickname(s) | JK or Jay Kay |
Ìgbà èwe àti aáyan ìṣèlú rẹ̀
àtúnṣeA bí Jìmí Agbájé ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Orúkọ àwọn òbí rẹ̀ ni Olóyè Julius Kòṣebínú (Banker) àti Ìyáàfin Margaret Ọlábísí (oluko) Agbájé. Òun ọmọ ìkejì tí àwọn òbí rẹ̀ bí, àkọ́bí ọmọ wọn ní ṣẹ́gun Agbájé, tí ó jẹ́, Alákòóso ilé ìfowópamọ́, Guaranty Trust Bank.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Isawade, Isa (2019-01-21). "Countdown to 2019: Profile of the PDP Lagos governorship candidate, Jimi Agbaje". P.M. News. Retrieved 2019-09-17.
- ↑ Published (2015-12-15). "Agbaje". Punch Newspapers. Retrieved 2019-09-17.