João Baptista de Oliveira Figueiredo
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Brazil
João Baptista de Oliveira Figueiredo (tí Pípè ni Potogí: [ʒuˈɐ̃w̃ baˈtistɐ di oliˈvejɾɐ fiɡejˈɾedu]; ni a bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kìíní ọdún 1918, ó sìn kú ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1999) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Brasil ati Aare orile-ede Brasil tẹ́lẹ̀.
João Baptista de Oliveira Figueiredo | |
---|---|
30th President of Brazil | |
In office March 15, 1979 – March 15, 1985 | |
Vice President | Aureliano Chaves |
Asíwájú | Ernesto Geisel |
Arọ́pò | Tancredo Neves |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Rio de Janeiro, Brazil | Oṣù Kínní 15, 1918
Aláìsí | December 24, 1999 Rio de Janeiro, Brazil | (ọmọ ọdún 81)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Brazilian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Renewal Alliance Party - ARENA |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |