Joe Jackson

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Joseph Walter Jackson (July 26, 1928 – June 27, 2018) je monija olorin ara Amerika ati baba-agba idile Jackson, Ohun ni baba Michael ati Janet Jackson. Won fi oruko re sinu Ile awon Olokiki Rhythm and Blues ni 2014.

Joe Jackson
Ọjọ́ìbíJoseph Walter Jackson
(1928-07-26)Oṣù Keje 26, 1928
Fountain Hill, Arkansas, U.S.
AláìsíJune 27, 2018(2018-06-27) (ọmọ ọdún 89)
Las Vegas, Nevada, U.S.[1]
Burial placeForest Lawn Memorial Park, Glendale, California, U.S.[2]
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iṣẹ́Talent manager
Ìgbà iṣẹ́1964–2018[3]
Olólùfẹ́
Katherine Scruse (m. 1949)
Àwọn ọmọ11 (see below), including Michael and Janet
ẸbíJackson
Websitejwjackson.com
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named LA
  2. Joe Jackson Buried in Same Cemetery as Son Michael
  3. Kevin Fleming (2017-04-07). "Joe Jackson to Receive the R&B Hall of Fame Living Legend Award". The Urban Buzz. Archived from the original on 2022-02-23. Retrieved 2019-11-09.