John Adams
Olóṣèlú
John Adams je oloselu omo ile Amerika. Wọ́n bí Adams ní 1735. Ó kú ní 1826. Òun ni ó jẹ President ilẹ̀ Àméríkà lẹ́yìn Washington. Òun ni ó kọ́kọ́ lọ ṣe ambassador ilẹ̀ oní-republic tuntun yìí ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.
John Adams | |
---|---|
2nd President of the United States | |
In office March 4, 1797 – March 4, 1801 | |
Vice President | Thomas Jefferson |
Asíwájú | George Washington |
Arọ́pò | Thomas Jefferson |
1st Vice President of the United States | |
In office April 21, 1789 – March 4, 1797 | |
Ààrẹ | George Washington |
Asíwájú | None |
Arọ́pò | Thomas Jefferson |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Quincy, Massachusetts, British America Àdàkọ:Country data Massachusetts | Oṣù Kẹ̀wá 30, 1735
Aláìsí | July 4, 1826 Quincy, Massachusetts, USA Àdàkọ:Country data Massachusetts | (ọmọ ọdún 90)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Federalist |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Abigail Smith Adams |
Àwọn ọmọ | Abigail Jr. (Nabby), John Quincy Adams, Susanna, Charles, Thomas and Elizabeth[stillborn] |
Alma mater | Harvard College |
Occupation | Lawyer |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |