Sir John Bertrand Gurdon (JBG), FRS (ojoibi 2 October 1933) je aseoroalaye onidagbasoke ara Britani. O gbajumo fun iwadi re ninu igbegbin onihaanu[2][3][4] and cloning.[5][1][6][7] Won fun ni Ebun Lasker ni 2009. Ni 2012, ohun ati Shinya Yamanaka gba Ebun Nobel fun Iwosan fun iwari won pe awon ahamo to ti dagba se sodi ahamo onihu.[8]

John Gurdon
ÌbíJohn Bertrand Gurdon
2 Oṣù Kẹ̀wá 1933 (1933-10-02) (ọmọ ọdún 91)
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish
PápáDevelopmental biology
Ilé-ẹ̀kọ́University of Oxford
University of Cambridge
California Institute of Technology
Ibi ẹ̀kọ́Christ Church, Oxford
Doctoral advisorMichael Fischberg[1]
Ó gbajúmọ̀ fúnNuclear transfer, cloning
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síWolf Prize in Medicine (1989)
Albert Lasker Basic Medical Research Award (2009)
Nobel Prize in Physiology or Medicine (2012)