John Howard
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Australia
John Winston Howard, AC (ojoibi 26 July 1939) je tele Alakoso Agba 25th orile-ede Australia, lati 11 March 1996 de 3 December 2007. Ohun ni Alakoso Agba Ostrelia keji to pejulo lori aga leyin Sir Robert Menzies.
John Howard | |
---|---|
25th Prime Minister of Australia
Elections: 1987, 1996–2007 | |
In office 11 March 1996 – 3 December 2007 | |
Deputy | Tim Fischer (1996–1999) John Anderson (1999–2005) Mark Vaile (2005–2007) |
Asíwájú | Paul Keating |
Arọ́pò | Kevin Rudd |
29th Treasurer of Australia | |
In office 19 November 1977 – 11 March 1983 | |
Asíwájú | Phillip Lynch |
Arọ́pò | Paul Keating |
Member of the Australian Parliament for Bennelong | |
In office 18 May 1974 – 24 November 2007 | |
Asíwájú | John Cramer |
Arọ́pò | Maxine McKew |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Keje 1939 Sydney, New South Wales, Australia |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Liberal Party of Australia |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Janette Howard |
Alma mater | University of Sydney |
Profession | Solicitor |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |