John Okechukwuemeka

Olóṣèlú

John Okechukwuemeka jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ mínísítà ìpínlẹ̀ tẹ́lẹ̀ fún ètò ìgbòkègbodò ọkọ̀ tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà látàrí ètò ìdìbò ti Oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]

John Okechukwuemeka
Mínísítà ìpínlẹ̀ tẹ́lẹ̀ fún ètò ìgbòkègbodò ọkọ̀
In office
Oṣù keje Ọdún 2007 – Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹwá Ọdún 2008
Aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Oṣù karún Ọdún 2011
AsíwájúAlphonsus Obi Igbeke
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Keje 1962 (1962-07-18) (ọmọ ọdún 62)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-04. 
  2. "New List of Federal Ministers of Nigeria & Their Ministries - After Yar'Adua Drops 20 Ministers.". Nigerian Muse. October 29, 2008. Retrieved 2011-05-04.