Joplin jẹ́ ilù kàn ní apá gúúsù Ibile Jasper àti apá áríwa Ibile Newton ní apá gúúsù iwọ

Joplin, Missouri
Ìlú
Aerial view of downtown Joplin, 2009
Aerial view of downtown Joplin, 2009
Motto(s): 
"Proud of Our Past...Shaping Our Future'"
ibudo ni ipinle Missouri
ibudo ni ipinle Missouri
IbileOrile-ede Amerika
IpinleMissouri
Àwọn ibileJasper, Newton
Incorporated1873
Government
 • MayorMelodee Colbert-Kean
Area
 • TotalÀdàkọ:Infobox settlement/metric/mag
 • Land81.4 km2 (31.4 sq mi)
 • Water0.2 km2 (0.1 sq mi)
Elevation
306 m (1,004 ft)
Population
 • Total50,150
 • Density610/km2 (1,600/sq mi)
Time zoneUTC-6 (CST)
 • Summer (DST)UTC-5 (CDT)
ZIP codes
64801-64804
Area code(s)417
FIPS code29-37592[2]
GNIS feature ID0729911[3]
WebsiteJoplinMO.org
oòrùn ìpínlẹ̀ Missouri ní orílè èdè Amerika. Joplin ní ìlú tí ó tóbì jù lọ Ìbílẹ̀ Jasper bó tilẹ̀ jẹ́ pé kíì ṣe ibùjókòó ìjọba ìbílẹ̀. Títí ìgbà ìkànìyàn 2010, ìlú náà ní àlábùgbè tótó 50,150.[1]  Ní 2010, àgbègbè tó yíká Metropolitan Statistical Area ní àlábùgbè tótó 175,518.[4]


ItokasiÀtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "2010 City Population and Housing Occupancy Status". U.S. Census Bureau. Retrieved May 23, 2011. 
  2. "American FactFinder". United States Census Bureau. Retrieved 2008-01-31. 
  3. "US Board on Geographic Names". United States Geological Survey. 2007-10-25. Retrieved 2008-01-31. 
  4. "Joplin, MO MSA Population and Components of Change". Recenter.tamu.edu. Retrieved May 24, 2011.