Joseph Akahan
Joseph Akahan (12 April 1937 - May 1968) jẹ́ ọ̀gá ológun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti oṣù karún ọdún 1967 sí karún ọdún 1967, tí ó sì kú látàrí ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú tí ó wáyé nígbà ogun abẹ́lé Nàìjíríà.[1][2]
Joseph Akahan | |
---|---|
Ọ̀gá ológun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà | |
In office Oṣù karún ọdún 1967 – Oṣù karún ọdún 1968 | |
Asíwájú | Yakubu Gowon |
Arọ́pò | Hassan Katsina |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kejìlá Oṣù karún ọdún 1937 Gboko LGA, Ipinle Benue, Nigeria |
Aláìsí | May 1968 | (ọmọ ọdún 31)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Chronicle of Command". The Nigerian Army. Retrieved 2010-06-01.
- ↑ Dr. Nowa Omoigui. "BARRACKS: THE HISTORY BEHIND THOSE NAMES (PART 7 - EPILOGUE Section 1)". Dawodu. Retrieved 2010-06-01.