Yakubu Gowon

Olóṣèlú

[1][2]Yakubu tí àpèjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Jack Dan-Yumma Gowon ni wọ́n bí ní kọkàndínlógún oṣù Kẹwàá, ọdún 1934 (19-10-1934) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti apá Àríwá. Gowon jẹ́ Ọ̀gágun ní Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ni ó sì tún jẹ̀ olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ódún 1966 dé 1971. Kásìkò ìjọba rẹ̀ náà ni ilẹ̀ Nàìjíríà ja ogun abẹ́lé láti 1966 sí 1971, lábẹ́ ogágun Odumegwu Ojukwu tí ó fẹ́ gba òmìnira lọ́wọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà.[3] [4]

Yakubu Gowon
Olori Orile-ede Naijiria 3k
In office
1 August 1966 – 29 July 1975
Vice PresidentJ.E.A Wey gegebi Chief of Staff, Supreme Headquarters
AsíwájúJohnson Aguiyi-Ironsi
Arọ́pòMurtala Mohammed
Oga Omose Agbogun
In office
January 1966 – July 1966
AsíwájúJohnson Aguiyi-Ironsi
Arọ́pòJoseph Akahan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kẹ̀wá 1934 (1934-10-19) (ọmọ ọdún 90)
Kanke, Plateau State, Naijiria
(Àwọn) olólùfẹ́Victoria Gowon
Alma materRoyal Military Academy Sandhurst
University of Warwick
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Adigun Nàìjíríà
Years of service1954–1975
RankOgagun

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "Video: Watch Gen Gowon’s reaction as he was told he had been overthrown". P.M. News. 2019-04-25. Retrieved 2019-10-15. 
  2. "Keyamo Replies Obasanjo: Yakubu Gowon Is The Boss Of All Bosses". Sahara Reporters. 2019-03-06. Archived from the original on 2019-10-15. Retrieved 2019-10-15. 
  3. "Yakubu Gowon - head of state of Nigeria". Encyclopedia Britannica. 1934-10-19. Retrieved 2019-10-15. 
  4. "THROWBACK: How Yakubu Gowon reacted to removal from office 43 years ago". Premium Times Nigeria. 2019-04-28. Retrieved 2019-10-15.