Joseph Ayo Babalola

Alàgbà Àkọ́kọ́ ti Ìjọ́ Apostolic Christ.
(Àtúnjúwe láti Joseph Ayọ́ Babalọlá)

Joseph Ayo Babalola (25 Kẹrin 1904 – 26 Keje 1959) jẹ́ mínísítà Kristiani ní Nàìjíríà àti adarí ijo Kristi Aposteli, tí gbogbo ènìyàn ń pè ni CAC ní Naijiria . Àjíhìnréré ìwòsàn ní.

Igbesi aye ibẹrẹ

àtúnṣe

Ihinrere àti ìwòsàn

àtúnṣe

Ní 1931 Faith Tabernacle tí wọn ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì pẹlu ilé-iṣẹ gbògbògbò ni United Kingdom (kì í ṣe Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì tí Ìlú Gẹẹsi, gẹ́gẹ́ bí àṣìṣe tí àwọn onkọwe kan sọ). [1] Lẹ́yìn ìpínyà tó wáyé ni ile-ìjọsìn The Apostolic ní ọdún 1940, Babalola lo pẹ̀lú ẹgbẹ́ kan ti Pátísò JB Akinyele ati DO Odubanjo jẹ olórí láti da ìjọ Olómìnira sílè, [2] Christ Apostolic Church (CAC), níbi ti o si tèsíwájú nínú ìwòsàn àti ihinrere rẹ títí o fí kú.

CAC ka Babalola gẹ́gẹ́ bi Àpóstèlì, bí o tilẹ̀ jẹ pé a kò fi si ọfiisi yẹn. A ti kọ ilé-iṣẹ ifẹ̀hìnsì CAC si Ipo Arakeji, Ipinle Osun nibiti wọn tí pé Babalola ní ọdún 1928. Síbẹ̀síbẹ̀, Babalola kì í ṣe òlùdásílẹ̀ ti CAC nìkan bi ọpọlọpọ ṣe sọ, ṣùgbọ́n ọkàn nínú àwọn òlùdásílẹ̀ mẹ́ta. [3]

Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì Kristi kọjá Babalola o si dàgbà, pẹ̀lú ọpọlọpọ àwọn ìjọsìn lábẹ́ orúkọ CAC. Ilé-ìjọsìn kọọkan ní orúkọ ẹka kan pàtó. Joseph Ayo Babalola University (JABU) ilé- ẹkọ giga Naijiria aládàní kàn wà ni Ipo Arakeji ati Ikeji-Arakeji. Àwọn àgbègbè méjì tó wa nítòsí nipinle Osun, ti ìjọ Christ Apostolic Church Worldwide tí a da sílè ni orúkọ rẹ, níbi tí ó ti pé Ọlọ́run pé òun ni ọdún 1928.


See also

àtúnṣe
  • Cornelius Adam Igbudu

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. (1). S.A. Fatokun(2006), "The Apostolic Church Nigeria: The ‘Metamorphosis’ of an Indigenous-Prophetic Healing Movement into a Classical Pentecostal Denomination" in Orita – Ibadan Journal of Religious Studies, Vol. 38, June & Dec., pp.49-70.http://www.oritajournal.org
  2. (2). S.A. Fatokun(2005), "Pentecostalism in Nigeria with Particular Emphasis on The Apostolic Church in Southwestern Nigeria", PhD Thesis, Department of Religious Studies, University of Ibadan, Nigeria
  3. (3)S.E.A. Oludare (1999), "The Trio of CAC Founding Fathers", M.A. Dissertation, Department of Religious Studies, University of Ibadan, Nigeria.