Joseph Ayo Babalola
Joseph Ayo Babalola (25 Kẹrin 1904 – 26 Keje 1959) jẹ́ mínísítà Kristiani ní Nàìjíríà àti adarí ijo Kristi Aposteli, tí gbogbo ènìyàn ń pè ni CAC ní Naijiria . Àjíhìnréré ìwòsàn ní.
Igbesi aye ibẹrẹ
àtúnṣeIhinrere àti ìwòsàn
àtúnṣeNí 1931 Faith Tabernacle tí wọn ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì pẹlu ilé-iṣẹ gbògbògbò ni United Kingdom (kì í ṣe Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì tí Ìlú Gẹẹsi, gẹ́gẹ́ bí àṣìṣe tí àwọn onkọwe kan sọ). [1] Lẹ́yìn ìpínyà tó wáyé ni ile-ìjọsìn The Apostolic ní ọdún 1940, Babalola lo pẹ̀lú ẹgbẹ́ kan ti Pátísò JB Akinyele ati DO Odubanjo jẹ olórí láti da ìjọ Olómìnira sílè, [2] Christ Apostolic Church (CAC), níbi ti o si tèsíwájú nínú ìwòsàn àti ihinrere rẹ títí o fí kú.
CAC ka Babalola gẹ́gẹ́ bi Àpóstèlì, bí o tilẹ̀ jẹ pé a kò fi si ọfiisi yẹn. A ti kọ ilé-iṣẹ ifẹ̀hìnsì CAC si Ipo Arakeji, Ipinle Osun nibiti wọn tí pé Babalola ní ọdún 1928. Síbẹ̀síbẹ̀, Babalola kì í ṣe òlùdásílẹ̀ ti CAC nìkan bi ọpọlọpọ ṣe sọ, ṣùgbọ́n ọkàn nínú àwọn òlùdásílẹ̀ mẹ́ta. [3]
Ilé-ìjọsìn Àpóstèlì Kristi kọjá Babalola o si dàgbà, pẹ̀lú ọpọlọpọ àwọn ìjọsìn lábẹ́ orúkọ CAC. Ilé-ìjọsìn kọọkan ní orúkọ ẹka kan pàtó. Joseph Ayo Babalola University (JABU) ilé- ẹkọ giga Naijiria aládàní kàn wà ni Ipo Arakeji ati Ikeji-Arakeji. Àwọn àgbègbè méjì tó wa nítòsí nipinle Osun, ti ìjọ Christ Apostolic Church Worldwide tí a da sílè ni orúkọ rẹ, níbi tí ó ti pé Ọlọ́run pé òun ni ọdún 1928.
See also
àtúnṣe- Cornelius Adam Igbudu
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ (1). S.A. Fatokun(2006), "The Apostolic Church Nigeria: The ‘Metamorphosis’ of an Indigenous-Prophetic Healing Movement into a Classical Pentecostal Denomination" in Orita – Ibadan Journal of Religious Studies, Vol. 38, June & Dec., pp.49-70.http://www.oritajournal.org
- ↑ (2). S.A. Fatokun(2005), "Pentecostalism in Nigeria with Particular Emphasis on The Apostolic Church in Southwestern Nigeria", PhD Thesis, Department of Religious Studies, University of Ibadan, Nigeria
- ↑ (3)S.E.A. Oludare (1999), "The Trio of CAC Founding Fathers", M.A. Dissertation, Department of Religious Studies, University of Ibadan, Nigeria.