Joseph E. Stiglitz
Joseph Eugene Stiglitz, ForMemRS, FBA, (ojoibi February 9, 1943) je ara Amerika aseoro-okowo ati ojogbon ni Yunifasiti Kolumbia. O gba Ebun Iranti Nobel fun awo Sayensi Oro-Okowo (2001) ati Eso John Bates Clark (1979).
Joseph Stiglitz | |
---|---|
17th Chair of the Council of Economic Advisors | |
In office 1995–1997 | |
Ààrẹ | Bill Clinton |
Asíwájú | Laura Tyson |
Arọ́pò | Janet Yellen |
World Bank Chief Economist | |
In office 1997–2000 | |
Asíwájú | Michael Bruno |
Arọ́pò | Nicholas Stern |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Kejì 1943 Gary, Indiana |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Anya Schiffrin |
Alma mater | Amherst College Massachusetts Institute of Technology |
Profession | Economist |
New Keynesian economics | |
---|---|
Field | Macroeconomics, Public Economics, Information Economics |
Influences | John Maynard Keynes, Robert Solow |
Influenced | Paul Krugman, Jason Furman |
Contributions | Screening, Taxation, Unemployment |
Information at IDEAS/RePEc |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |