Josip Broz Tito
Josip Broz Tito (bibi bi Josip Broz; 7 or 25 May 1892 – 4 May 1980) je ara ile Yugoslafia to je olujidide ati agbailu.[1] Ohun lo je Akowe Agba (o di Aare leyin) Egbe awon Komunisti ile Yugoslafia (1939–80), o si lewaju irinkankan agbogun Yugoslafia nigba Ogun Agbaye Keji, ati awon Partisan Yugoslafia (1941–45).[2] After the war, he was the authoritarian[3][4][5] Alakoso Agba (1943–63) ati leyin re Aare (1953–80) Orile-ede Olominira Sosialisti Apapo (SFRY). Lati 1943 di ojo iku re ni 1980, o di ipo Kakanfo ile Yugoslafia mu, nibi to ti je alase patapata ile ise ologun Yugoslafia, eyun Yugoslav People's Army (JNA).
Tito lo je bi eni to sedasile "Yugoslafia keji", ile apapo sosialisti to wa lati Ogun Agbaye Keji de 1991. Botilejepe o je ikan ninu awon oludasile egbe Cominform, ohun na tun ni eni akoko (ti yio yori si rere) omo egbe Cominform to lodi si ilelori Sofieti.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
ItokasiÀtúnṣe
- ↑ "Josip Broz Tito". Encyclopædia Britannica Online. Retrieved 27 April 2010.
- ↑ Bremmer, Ian (2007). The J Curve: A New Way to Understand Why Nations Rise and Fall. Simon & Schuster. p. 175. ISBN 0743274725.
- ↑ Cohen, Mark F.; Fidler, Jay W. (2002). Group Psychotherapy and Political Reality: A Two-Way Mirror. International Universities Press. p. 193. ISBN 0823622282.
- ↑ Andjelic, Neven (2003). Bosnia-Herzegovina: The End of a Legacy. Frank Cass. p. 36. ISBN 071465485X.
- ↑ Tierney, Stephen (2000). Accommodating National Identity: New Approaches in International and Domestic Law. Martinus Nijhoff Publishers. p. 17. ISBN 9041114009.