Joyce Banda
Joyce Hilda Banda née Mtila (ojoibi 12 April 1950) je oloselu are Malawi to ti unse Aare ile Malawi lati ojo 7 Osu Kerin 2012. Banda je oluko ati alakitiyan eto awon obinrin. O wa nipo bi Alakoso Aro Okere lati 2006 de 2009 ati Igbakeji Aare ile Malawi lati May 2009 de April 2012.[2] Banda took office as President following the sudden death of President Bingu wa Mutharika. Ohun ni aare ikerin ile Malawi[3] ati aare akoko to je obinrin.
Joyce Banda | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 7 April 2012 | |
Vice President | Khumbo Kachali |
Asíwájú | Bingu wa Mutharika |
Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì | |
In office 29 May 2009 – 7 April 2012 | |
Ààrẹ | Bingu wa Mutharika |
Asíwájú | Cassim Chilumpha |
Arọ́pò | Khumbo Kachali |
Alakoso Oro Okere | |
In office 1 June 2006 – 29 May 2009 | |
Ààrẹ | Bingu wa Mutharika |
Asíwájú | George Chaponda |
Arọ́pò | Etta Banda |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹrin 1950 Malemia, Nyasaland (now Malawi) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Democratic Front (Before 2004) Democratic Progressive Party (2004–2010) People's Party (2011–present) |
{{{blank1}}} | Roy Kachale (de 1981) Richard Banda[1] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedmalawi
- ↑ "Joyce Banda sworn in as new Malawi presiden". The BBC. 7 April 2012. Retrieved 7 April 2012.
- ↑ Mwagiru, Ciugu (18 April 2012). "Malawi's Joyce Banda and the rise of women in African politics". Daily Monitor online (Kampala, Uganda). http://www.monitor.co.ug/artsculture/Reviews/-/691232/1388740/-/diw45/-/. Retrieved 19 April 2012.