Juan Manuel Santos Calderón
(Àtúnjúwe láti Juan Manuel Santos)
Orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè Spéìn; àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni Santos èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni Calderón.
Juan Manuel Santos Calderón (ojoibi 10 August 1951) je oloselu ara Kolombia, Alakoso Eto Abo tele, ati lowolowo Aare orile-ede Kolombia lati 7 Osu Kejo, 2010, leyin ti o bori ninu idiboyan aare Kolombia 2010.[1]
Juan Manuel Santos Calderón | |
---|---|
59th President of Colombia | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 7 August 2010 | |
Vice President | Angelino Garzón |
Asíwájú | Álvaro Uribe |
Minister of National Defense | |
In office 19 July 2006 – 18 May 2009 | |
Ààrẹ | Álvaro Uribe |
Asíwájú | Camilo Ospina Bernal |
Arọ́pò | Freddy Padilla de León |
Minister of Finance and Public Credit | |
In office 7 August 2000 – 7 August 2002 | |
Ààrẹ | Andrés Pastrana |
Asíwájú | Juan Camilo Restrepo |
Arọ́pò | Roberto Junguito Bonnet |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹjọ 1951 Bogotá, Colombia |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Party of National Unity |
(Àwọn) olólùfẹ́ | María Clemencia Rodríguez |
Alma mater | University of Kansas London School of Economics Harvard University Fletcher School of Law and Diplomacy |
Profession | Economist |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Ex ministro de Defensa de Uribe presenta candidatura presidencial". CNN México. 2010-02-27. Archived from the original on 2010-03-01. https://web.archive.org/web/20100301010719/http://www.cnnmexico.com/mundo/2010/02/27/ex-ministro-de-defensa-de-uribe-presenta-candidatura-presidencial. Retrieved 2010-02-27.