Juliana Olayode
(Àtúnjúwe láti Juliana Olóyèdé)
Juliana Olúwatóbilọ́ba Ọláyọdé, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Toyo Baby, nípa ipa tí ó kó nínú eré Jenifa's Diary gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀dá-ìtàn, Tóyọ̀sí jẹ́ Òṣèrébìnri sinimá àgbéléwò àti ti tẹlifíṣàn, ó tún jẹ́ aṣègbè fún ìbálòpọ̀-ẹ̀tọ́ ọmọ Nàìjíríà.[1][2][3] Ó tún jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká nípa àtakò rẹ̀ sí ìbálòpọ̀ lọ́kọláya láìṣe ìgbéyàwó tó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọ̀dọ́.[4]
Juliana Olayode | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Juliana Olúwatóbilọ́ba Olóyèdé 7 Oṣù Kẹfà 1995 Èkó , Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Toyo Baby |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnri , Oǹkọ̀wé, Asọ̀rọ̀móríyá |
Ìgbà iṣẹ́ | Ọdún 2015 títí di òní yìí |
Ìgbésí-ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀
àtúnṣeA bí Juliana sí ìlú Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ bibi ìjọba ìbílẹ̀ Ìpókíá ní Ìpínlẹ̀ Ògùn.[5][6]Nígbà èwe rẹ̀, kò tilẹ̀ lálàá pé òun lè di òṣèrébìnri, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó máa ń kópa nínú àwọn eré ìtàgé dáadáa.[7]
Àtòjọ àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀
àtúnṣeÓ ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò, lára wọn ni: [8]
- Jenifa's Diary[9][10]
- Where Does Beauty Go
- Rivers Between[11]
- Couple of Days[12]
- Life of disaster
- Move on
- Bridezilia
- The Cokers
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "People shouldn’t have sex until they are married— Juliana Olayode aka Toyo Baby". Punch. 2 April 2017. Retrieved 6 September 2017.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-09-06. Retrieved 2020-11-03.
- ↑ John Owen Nwachukwu (18 August 2017). "How I gave my virginity to my married music teacher – Actress Toyo Baby". DailyPostNg. Retrieved 6 September 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-09-10. Retrieved 2020-11-03.
- ↑ "Most times I Reject Roles that are Not in Line With my Beliefs - Juliana "Toyo Baby" Olayode"". BellaNaija. 2 April 2017. Retrieved 6 September 2017.
- ↑ Dupe Ayinla-Olayinsukanmi (26 September 2016). "Why i speak about my virginity - Toyo Baby". Thenation. Retrieved 6 September 2017.
- ↑ http://punchng.com/people-shouldnt-have-sex-until-they-are-married-juliana-olayode-aka-toyo-baby/
- ↑ ""8 Things We Never Knew About Toyo Baby!"". woman.ng. woman.ng. Archived from the original on 28 June 2017. Retrieved 11 May 2017.
- ↑ ""JENIFA’S DIARY HAS BROUGHT ME FAME- NOLLYWOOD ACTRESS OLAYODE JULIANA AKA (TOYOSI)". dailymedia.com.ng. Archived from the original on 17 November 2017. Retrieved 11 May 2017.
- ↑ ""PHOTOS: MEET NOLLYWOOD ACTRESS FUNKE AKINDELE’S JENIFA’S DIARY TV SERIES CAST MEMBERS/ACTORS". dailymedia.com.ng. Archived from the original on 17 November 2017. Retrieved 11 May 2017.
- ↑ "Olayode Juliana, steadily killing it"#WomanCrushWednesday". Pulse.ng. 1 January 2017. Retrieved 6 September 2017.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ ""WHY I SPEAK ABOUT MY VIRGINITY –TOYO BABY". The Nation. DUPE AYINLA-OLASUNKANMI. Retrieved 11 May 2017.