Jumoke Odetola jẹ́ òṣèrébìnrin órílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2][3][4]

Olajumoke Odetola
Ọjọ́ìbíOlajumoke Odetola
16 Oṣù Kẹ̀wá 1983 (1983-10-16) (ọmọ ọdún 41)
Eko,Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaAjayi Crowther University
Iṣẹ́Actress | Model | Producer

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́

àtúnṣe

Wọ́n bí Jumoke Odetola lọ́jọ́ kerindinlógún oṣù Kewa ọdún 1983 si ilu Èkó. Jumoke jẹ́ abikeyin ninu ọmọ meje tí àwọn òbí rẹ̀ bí.[5] Ó lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ ABATI Nur/Pry School ní Ìpínlẹ̀ Èkó,ti o si lo ile -iwe girama ti o wa ni Abeokuta ( Abeokuta Grammar School)Ó lọ sí Yunifásítì Ajayi Crowther ( Ajayi Crowther University).

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Bada, Gbenga (April 9, 2016). "'Boyfriends are distractions,' AMVCA's best indigenous act says". Pulse Nigeria. Retrieved May 21, 2022. 
  2. "Jumoke Odetola bags 100 Most Influential Young Leaders in Nigeria award". Tribune Online. April 2, 2022. Retrieved May 21, 2022. 
  3. Olawale, Gabriel (February 20, 2022). "Jumoke Odetola bags Ambassadorial deal with Success Foods". Vanguard News. Retrieved May 21, 2022. 
  4. "Actress Jumoke Odetola Causes A Stir As She Shares Loved-up Photos Of Herself With Popular Actor". Global Times Nigeria. February 22, 2022. Archived from the original on February 22, 2022. Retrieved May 21, 2022. 
  5. "My father never wanted me to become an actress - Jumoke Odetola". Tribune Online. March 5, 2021. Retrieved May 21, 2022.