Justin Ahomadégbé-Tomêtin

Justin Ahomadégbé-Tomêtin je ara orile-ede Benin ati Aare ile Benin tele.

Ipade ti Alakoso Agba Israeli Lefi Eshkol ati iyawo rẹ Miriam Eshkol pelu Alakoso Agba Dahomey Justin Ahomadégbé-Tomêtin nigba abewo won si ilu Parisi, ọjọ kẹta oṣu keje ọdun 1964.


ItokasiÀtúnṣe