Juyik (Persian: جوئيک‎‎, jẹ́ Jūyīk ní èdè Latini ;a tún lépè ní Jūyīg)[1] jẹ́ abúlé ní agbèègbè Bahu Kalat, agbèègbè Dashtiari, Sistan àti ìgbèríko Baluchestan, Ìránì. Ní Ìkànìyàn ọdún 2006, gbogbo ènìyaǹ tó ń gbé ní abúlé yìí jẹ́ igba àti mẹtàléláàdọ̀rín nínú ẹbí mẹ́rìndínláàdóta.[2]

Juyik

جوئيک
Abúlé
Country Iran
ProvinceSistan and Baluchestan
CountyChabahar
BakhshDashtiari
Rural DistrictBahu Kalat
Population
 (2006)
 • Total273
Time zoneUTC+3:30 (IRST)
 • Summer (DST)UTC+4:30 (IRDT)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Juyik can be found at GEOnet Names Server, at this link, by opening the Advanced Search box, entering "-3766715" in the "Unique Feature Id" form, and clicking on "Search Database".
  2. "Census of the Islamic Republic of Iran, 1385 (2006)".