Kayode Olasehinde
(Àtúnjúwe láti Káyọ̀dé Ọlásẹ̀hìndé)
Kayode Olasehinde tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Pa James ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kẹfà ọdún 1957 (4th June 1957)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ aláwàdà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ òṣèré nínú eré àwàdà tẹlifíṣàn tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Bàbá Ajasco. Kódà nínú eré yìí ni wọ́n ti sọ ó ní orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ Pa Jame. Káyọ̀dé Ọlásẹ̀yìndé ni bàbá Samuel Ọlásẹ̀yìndé, ọ̀dọ́mọdé òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan, ṣùgbọ́n tí ó ti dàgbà gẹ́gẹ́ bí òṣèré bákan náà. [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Kayode Olasehinde Pa James: Biography - Filmography - Awards". Flixanda. 1957-06-04. Archived from the original on 2020-01-11. Retrieved 2020-01-11.
- ↑ Published (2015-12-15). "Dad is a no-nonsense person, he is only comical in movies – Pa James’ son". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-11.