Kẹ̀kẹ́ Alùpùpù

Kẹ̀kẹ́ Alùpùpù[1]) ni kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ méjì tí ó ń lo ẹngìnì àti epo bẹntiróò láti fi rìn ní ojú pópó. Wọ́n fún kẹ̀kẹ́ alùpùpù yí ní orúkọ ìbílẹ̀ rẹ̀ Ọ̀kadà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní àfijọ ọkọ̀ òfurufú kan Okada Air tí ó wà ní àrọko Ìpínlẹ̀ Benin amọ́ tí kò sí mọ́. Kẹ̀kẹ́ alùpùpù ni ó wọ́pọ̀ jùlọ ní apá Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀, nítorí ìjá fáfá rẹ̀ láti gbéni dé ibi tí ènìyàn ń lọ lásìkò. [2]

Okada in Kano, Nigeria

Àwọn orílẹ̀-èdè tí kẹ́ké alùpùpù ti wọ́pọ̀ jùlọ

àtúnṣe

Orílẹ̀-èdè [Togo]] orúkọ tí wọ́n ń pèé : (oléyia). Orílẹ̀-èdè Benin orúkọ tí wọ́n ń pèé : (zémidjans) Orílẹ̀-èdè Burkina Faso Orílẹ̀-èdè Liberia orúkọ tí wọ́n ń pèé : (phen-phen) àti orílẹ̀-èdè Sierra Leone.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The impact of Inaga ban on students". www.thenationonlineng.com. The Nation (Lagos), Thursday, 18 June 2009. Retrieved 2009-12-27. 
  2. Ezeibe, Nzeadibe, Ali, Udeogu, Nwankwo and Ogbodo (2017). "Work on wheels: collective organising of motorcycle taxis in Nigerian cities". IDPR 39 (3): 249–273. doi:10.3828/idpr.2017.10. 
  3. Mbella Mouelle, S. L. (2014). Complex causality between transportation and human security: A special focus on the city of douala, cameroon http://search.proquest.com/docview/1625048725/