Kola Tubosun
Oníwé-Ìròyín
(Àtúnjúwe láti Kọ́lá Túbọ̀sún)
Kọ́lá Túbọ̀sún jẹ́ akọ́mọlédè, oǹkọ̀wé, ọ̀mọ̀wé ati olùgbásàga ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [1][2][3] tí iṣẹ́ ipa rẹ̀ ti gbajúmọ̀ ní ọ̀pọ̀ ẹ̀ka èkọ́, ìmọ̀-ẹ̀rọ, lítírésọ̀, ìròyìn, ati ẹ̀ka akọ́mọlédè. O jẹ́ aṣojú àṣà ni (Southern Illinois University Edwardsville, 2009), Ó ti gba àkànṣe àmì-é̀yẹ Premio Ostana fuń litireṣọ̀ èdè abínibí lọ́dún.[4][5][6] Ó jẹ́ oǹkọ̀wé èdè Yorùbá àti Gèésì.
Kọ́lá Túbọ̀sún | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kọ́láwọlé Olúgbémiró Ọlátúbọ̀sún (Ọ̀ládàpọ̀) 22 Oṣù Kẹ̀sán 1981 Ibàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Kọ́lá Ọlátúbọ̀sún |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan, Moi University, Southern Illinois University Edwardsville |
Iṣẹ́ | Akọ́mọlédè, Oǹkòwé, Olùkó |
Ọmọ ìlú | Ibàdàn |
Alábàálòpọ̀ | Temie Gíwá |
Parent(s) | Ọlátúbọ̀sún Ọládàpọ̀ |
Website | ktravula.com |
Ìtàn ayé rẹ̀
àtúnṣeA bí Tubosun ní ìlú Ibadan, Nàìjíríà ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1981. Ó ní àmì ẹyẹ Masters nínú ìmọ̀ Linguistics ní Southern Illinois University Edwardsville (ọdún 2012) àti àmì ẹyẹ BA ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn (ọdún 2005). Ó tún kàwé fún ìgbà díẹ̀ ní Yunifásitì Moi, Eldoret, Kenya ní oṣù kẹrin ọdún 2005.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Olofinlua, Temitayo (25 May 2015). "Nigerian Scholar Creates an Online Home for Yoruba Names". Global Press Journal. Global Press. Archived from the original on 4 September 2015.
With the help of volunteers and crowdsourcing contributors, he is creating an online compendium of Yoruba names with meanings and aural pronunciations.
- ↑ "A Stroll with Kola Tubosun, Teacher, Writer, Linguist and Founder, YorubaName.com"
- ↑ "Writing a New Nigeria: Ideas of Identity", BBC Radio 4,
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Uhakheme, Ozolua (25 January 2016). "Nigerian author wins Premio Ostana award for scriptures". The Nation.
- ↑ "Giunge a conclusione l'ottava edizione del Premio Ostana". Retrieved 2016-06-06.