Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede ni Ìlaòrùn Áfríkà. O dubule si eba Okun India, ni agedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode mo Ethiópíà (ariwa), Sòmálíà (ariwailaorun), Tànsáníà (guusu), Ùgándà ati Lake Victoria (iwoorun), ati Orile ede Gúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re ni Nairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.

Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Harambee"  (Swahili)
"Let us all pull together"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèEe Mungu Nguvu Yetu
"O God of All Creation"

(àti ìlú títóbijùlọ) Nairobi
Èdè àlòṣiṣẹ́ Swahili, English[1]
Ìjọba Semi-presidential Republic
 -  President Uhuru Kenyatta
 -  Prime Minister Raila Odinga
Independence from the United Kingdom 
 -  Date December 12, 1963 
 -  Republic declared December 12, 1964 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 580,367 km2 (47th)
224,080 sq mi 
 -  Omi (%) 2.3
Alábùgbé
 -  Ìdíye July 2009 39,002,772[2] (32nd)
 -  8 February 2007 census 31,138,735 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 67.2/km2 (140th)
174.1/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $60.361 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,711[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $29.564 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $838[3] 
HDI (2007) 0.521 (medium) (148th)
Owóníná Kenyan shilling (KES)
Àkókò ilẹ̀àmùrè EAT (UTC+3)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+3)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ke
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +254
1. According to cia.gov, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected.[2]

Awon Igberiko, ibile ati awon ipinsiÀtúnṣe

 
Provinces of Kẹ́nyà

Kenya pinsi awon igberiko 8 ti olori won n je Alakoso Igberiko (Aare lo n yan won). Awon igberiko wonyi (mkoa singular mikoa plural in Swahili) na tun je pinpin si awon ibile (wilaya). Awon ibile 69 lo wa. Awon ibile wonyi na tun je pipin si awon ipinsi 497 (taarafa). Awon ipinsi tu je pipin si 2,427 awon ibudo 2,427 (mtaa) ati omo ibudo 6,612 (mtaa mdogo).[4]. Awon igberiko na niwonyi:

Iye awon onibugbe awon ilu ninlaÀtúnṣe

Ilu Iye eniyan
Nairobi 2 940 911
Mombasa 707 400
Nakuru 337 200
Kisumu 273 400
Eldoret 249 100
Nyeri 213 000
Machakos 179 500
Meru 140 900
ItokasiÀtúnṣe

  1. Constitution (1998) art. 53 "the official languages of the National Assembly shall be Kiswahili and English and the business of the National Assembly may be conducted in either or both languages."
  2. 2.0 2.1 Central Intelligence Agency (2009). "Kenya". The World Factbook. Retrieved January 23, 2010. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Kenya". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Central Bureaus of Statistics (Kenya): Census cartography: The Kenyan Experience