Kalifa Dienta
Kalifa Dienta (tí wọ́n bí ní 1 Oṣù Kínní, Ọdún 1940) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Málì.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ A Banna.[2] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ònkọ̀tàn àti olùyàwòrán.
Kalifa Dienta كاليفا دينتا | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kalifa Dienta 1 Oṣù Kínní 1940 Macina, Mali |
Orílẹ̀-èdè | Malian |
Iṣẹ́ | Director, assistant director, costume designer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1967–present |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "FILMS DIRECTED BY Kalifa Dienta". letterboxd. Retrieved 9 October 2020.
- ↑ "Review: Reviewed Work: Directory of African Film-Makers and Films by Keith Shiri". jstor. Retrieved 9 October 2020.