Kehinde
Kehinde (Omokehinde) jẹ́ orúkọ Yorùbá tí wọ́n ń fún ọmọ ìkejì nínú àwọn ìbejì tàbí ọmọ tí ó wá lẹ́yìn Taiwo.[1][2] Bí ó tilè jẹ́ wípé Taiwo ni ọmọ tí ó kókó wáyé, àwọn Yorùbá gbàgbó pé Kehinde ni ẹ̀gbọ́n, ṣùgbọ́n ó rán Taiwo wá sáyé láti wá "Tó ayé wò".[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Kehinde, Temitope (1975). "Ajayi". Online Nigeria. Retrieved January 31, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Kehinde". The Name meaning.
- ↑ Herman Bauman (2008). African Safari for Jesus. Xlibris Corporation. ISBN 978-1-462-8253-70. https://books.google.com/books?id=JY6QWgk56a8C&q=kehinde+is+the+older+twin&pg=PA46.