Kẹ́mi "Lala" Akindoju jẹ́ òṣèrè ọmọ Nàìjíríà kan. Ó gba ẹ̀bun Africa Magic kan fún ipa rẹ̀ nínu àṣàmùbádọ́gba fiimu Dazzling Mirage[1]

Kemi Lala Akindoju
Ọjọ́ìbíKemi Akindoju
8 Oṣù Kẹta 1987 (1987-03-08) (ọmọ ọdún 37)
Ipinle Eko, Nàìjíríà
Ẹ̀kọ́University of Lagos
Pan African University
Iṣẹ́Osere
Ìgbà iṣẹ́2005–lowolowo

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Akindoju ní ọjọ́ 8 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1987 ní ìdílé àwọn ọmọ mẹ́rin.[2] Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ondo. Ó lọ ilé-ìwé girama ti Queen's College, Ìpínlẹ̀ Èkó. Lẹ́hìn tí ó gba ìwé-ẹ̀rí tí ìdánwò West African Examinations Council (WAEC), ó tẹ̀síwájú láti kẹ́ẹ̀kọ́ nípa insurance ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásitì Èkó. Ó tún gba óyè gíga láti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Pan-Atlantic, níbi tí ó ti kẹ́ẹ̀kọ́ media áti communication.

Iṣẹ́-ìṣe

àtúnṣe

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2005 láti orí ìpele ṣááju kí́ ó tó lọ sińu àwọn sinimá àgbéléwò.[3]

Àwon àsàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ẹ̀bùn áti ìfisọrí rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "My parents are my strongest supporters — Kemi Lala Akindoju, winner, Trailblazer, AMVCA 2016". vanguardngr.com. Retrieved 12 June 2016. 
  2. "AMVCA Trailblazer award winner, Kemi Lala Akindoju turns 29 years old today". thenet.ng. Archived from the original on 5 April 2017. Retrieved 12 June 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "I’m nervous about my roles — Kemi Lala Akindoju". punchng.com. Retrieved 12 June 2016. 
  4. "Top 5 movies featuring the talented actress". pulse.ng. Archived from the original on 12 May 2016. Retrieved 12 June 2016.