Dazzling Mirage jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ọdún 2014, èyí tí Tunde Kelani darí, tí àwọn ọ̀ṣèré bíi Kemi Lala Akindoju, Kunle Afolayan, Bimbo Manuel, Yomi Fash Lanso, Taiwo Ajai-Lycett àti Seun Akindele kópa nínú rẹ̀.[2][3][4] Àwọn òṣèré mìíràn bíi Adewale Ayuba, Sean Tizzle, Tunde Babalola àti Steve Sodiya náà kópa nínú fíìmù yìí.[5] Fíìmù yìí jẹ́ àgbéjáde ti ìwé ìtàn àròsọ tí Olayinka Abimbola Egbokhare kọ, èyí tí Ade Solanke wá sọ di fíìmù àgbéléwò.[6] Fíìmù náà dá lórí ìtàn arábìnrin kan tó ní ìdojúkọ àìsàn sickle cell, pẹ̀lú àwọn ìpènijà tó ń kojú ní àwùjọ.

Dazzling Mirage
AdaríTunde Kelani
Olùgbékalẹ̀Tunde Kelani
Àwọn òṣèré
OrinMichael Ogunlade
Ìyàwòrán sinimá
  • Sarafa Abagun
  • Seun Sonoiki
OlóòtúMumin Kelani
Ilé-iṣẹ́ fíìmùMainframe Film and Television Productions
OlùpínFilmOne Distributions
Déètì àgbéjáde
  • 9 Oṣù Kẹ̀wá 2014 (2014-10-09) (New Zealand)
  • 7 Oṣù Kọkànlá 2014 (2014-11-07) (Muson Centre)
  • 20 Oṣù Kejì 2015 (2015-02-20)
Àkókò90 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Owó àrígbàwọlé₦13,000,000[1]

Àwọn akópa

àtúnṣe

Ìṣàgbéjáde

àtúnṣe

Ní oṣù kẹta ọdún 2012, ní kété tí wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù Maami, wọ́n ṣe ìkéde rẹ̀ Kelani á ṣe ìwé ìtàn àròsọ ti Olayinka Abimbola, ìyẹn Dazzling Mirage gẹ́gẹ́ bí i fíìmù.[7] Ní oṣù kìíní ọdún 2013, wọ́n sàrídájú pé ìpalẹ̀mọ́ erẹ́ náà ti bẹ̀rẹ̀.[8] Kelani gbàgbọ́ pé fíìmù náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọ n ọ̀nà tí òun fi lè dá sí ọ̀rọ̀ àwùjọ látàrí ètò ìlera, pàápàá jù lọ àwọn tó máa ń ní àìsàn fòníkú-fọ̀ladìde. Èròǹgba wọn ni pé àwọn ọ̀dọ́ á rí ẹ̀kọ́ kọ́ níbẹ̀.[9] Ó sọ wí pé: "gbogbo wa la ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn tó ní àìsàn yìí" "Èmi náà ti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn tó ní ìdojúkọ àìsàn yìí, mo sì ri gẹ́gẹ́ bí ojúṣe mi láti mú ìtàn wọn wá sí gbàgede."[10][11][12] [13]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Odejimi, Segun (18 January 2016). "IN FULL: TNS Exclusive Report On Nigerian Cinema In 2015". TNS. Archived from the original on 21 February 2016. Retrieved 20 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. George, Mayowa (21 February 2014). "Photos From The Set Of Tunde Kelani's New Movie, 'Dazzling Mirage'". 360 Nobs. Archived from the original on 16 September 2020. Retrieved 7 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Guardian
  4. "Tunde Kelani Marks World Sickle Cell Day with new movie, Dazzling 'Mirage'.". Ebonylife TV. 20 June 2014. Retrieved 7 August 2014. 
  5. "Tunde Kelani Releases Official Poster and Trailer for 'Dazzling Mirage'". Nollywood by Mindspace. 19 June 2014. Retrieved 7 August 2014. 
  6. Arogundade, Funsho (20 June 2014). "Tunde Kelani Releases 'Dazzling Mirage' Trailer". PM News Nigeria. PM News. Retrieved 7 August 2014. 
  7. "Dazzling Mirage by Olayinka Abimbola set to be adapted to the big screens by Tunde Kelani". 9jabooksandmovies. 10 March 2012. Retrieved 7 August 2014. 
  8. "Tunde Kelani's film adaptation Of 'Dazzling Mirage' commences!". 9jabooksandmovies. 22 January 2013. Retrieved 8 August 2014. 
  9. Jasanya Olamide (20 June 2014). "VIDEO: Watch Kunle Afolayan, Yomi Fash Lanso star in Dazzling Mirage [Trailer]". Nigerian Entertainment Today. The NET. Retrieved 7 August 2014. 
  10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Jaguda
  11. Obenson, Tambay A. (2 December 2013). "Watch First Trailer For Tunde Kelani's Feature Film Adaptation Of 'Dazzling Mirage'". IndieWire. Shadow and Act. Retrieved 8 August 2014. 
  12. "Tunde Kelani presents new movie, 'Dazzling Mirage'". Silverbird Group. Silverbird Cinemas. Archived from the original on 8 August 2014. Retrieved 8 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. "Dazzling Mirage latest! Day1 of shoot". Mainframe. 18 September 2013. Archived from the original on 27 February 2015. Retrieved 8 August 2014.