Kim Basinger

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Kim Basinger je osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Kim Basinger
Kim Basinger
Basinger at the 62nd Academy Awards in 1990
Ọjọ́ìbíKimila Ann Basinger
Oṣù Kejìlá 8, 1953 (1953-12-08) (ọmọ ọdún 69)
Athens, Georgia, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Georgia
Iṣẹ́
  • Actress
  • model
  • singer
Ìgbà iṣẹ́1976–present
Olólùfẹ́plain list
Alábàálòpọ̀Mitchell Stone
(2014–present)
Àwọn ọmọIreland Baldwin

Ìgbèsi Àyè Áràbinrin naaÀtúnṣe

Basinger ni a bini Athens, Georgia ni Ọdun 1953 fun An Lee (1925-2017) ati Donald Wade (1923-2016). Basinger jẹ alumna ti William Esper Studio fun performing arts ni Manhattan, New York City[2]. Ki Óṣèrè lóbinrin naa to gbàjumọ ni ó fẹ Tim Saunders, Dale Robinette ati Joe Namath. Ni Óṣù October, ọdun 1980, Kim fẹ Ron Synder-Britton ti wọn si pinya ni ọdun 1989.

Ni ọdun 1990, Kim pade ọkọ rẹ keji Alec Baldwin ti wọn si fẹ ara wọn ni óṣu August ni ọdun 1993 ti wọn si bi ọmọ óbinrin Ireland Eliesse Baldwin ti wọn bi ni Óṣu October, ọdun 1995[3]. Tọkọ Taya naa pinya ni ọdun 2002. Ni ọdun 2014, Kim fẹ Mitch Stone ti wọn si bẹrẹ si ni gbè pọ lati igba naa[4].

ẸkọÀtúnṣe

Basinger kẹkọ nipa Ballet lati ọmọ ọdun mẹta. Óṣèrè lóbinrin naa kẹkọ ni ilè iwè giga Georgia[5].

Àmi Ẹyẹ ati IdànilọlàÀtúnṣe

Kim gbà ami ẹyẹ ti Akademi, Àmi ẹyẹ ti Golden Globe, Àmi ẹyẹ ti Óṣèrè Screen Guils ati irawọ ti Hollywood Walk of Fame[6].

ItokasiÀtúnṣe