Kola Tubosun

Oníwé-Ìròyín

Kọ́lá Túbọ̀sún jẹ́ akọ́mọlédè, oǹkọ̀wé, ọ̀mọ̀wé ati olùgbásàga ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [1][2][3] tí iṣẹ́ ipa rẹ̀ ti gbajúmọ̀ ní ọ̀pọ̀ ẹ̀ka èkọ́, ìmọ̀-ẹ̀rọ, lítírésọ̀, ìròyìn, ati ẹ̀ka akọ́mọlédè. O jẹ́ aṣojú àṣà ni (Southern Illinois University Edwardsville, 2009), Ó ti gba àkànṣe àmì-é̀yẹ Premio Ostana fuń litireṣọ̀ èdè abínibí lọ́dún.[4][5][6] Ó jẹ́ oǹkọ̀wé èdè Yorùbá àti Gèésì.

Kọ́lá Túbọ̀sún
Ọjọ́ìbíKọ́láwọlé Olúgbémiró Ọlátúbọ̀sún (Ọ̀ládàpọ̀)
(1981-09-22)22 Oṣù Kẹ̀sán 1981
Ibàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànKọ́lá Ọlátúbọ̀sún
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan, Moi University, Southern Illinois University Edwardsville
Iṣẹ́Akọ́mọlédè, Oǹkòwé, Olùkó
Ọmọ ìlúIbàdàn
Alábàálòpọ̀Temie Gíwá
Parent(s)Ọlátúbọ̀sún Ọládàpọ̀
Websitektravula.com

Ìtàn ayé rẹ̀

àtúnṣe

A bí Tubosun ní ìlú Ibadan, Nàìjíríà ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1981. Ó ní àmì ẹyẹ Masters nínú ìmọ̀ Linguistics ní Southern Illinois University Edwardsville (ọdún 2012) àti àmì ẹyẹ BA ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn (ọdún 2005). Ó tún kàwé fún ìgbà díẹ̀ ní Yunifásitì Moi, Eldoret, Kenya ní oṣù kẹrin ọdún 2005.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Olofinlua, Temitayo (25 May 2015). "Nigerian Scholar Creates an Online Home for Yoruba Names". Global Press Journal. Global Press. Archived from the original on 4 September 2015. With the help of volunteers and crowdsourcing contributors, he is creating an online compendium of Yoruba names with meanings and aural pronunciations. 
  2. "A Stroll with Kola Tubosun, Teacher, Writer, Linguist and Founder, YorubaName.com"
  3. "Writing a New Nigeria: Ideas of Identity", BBC Radio 4,
  4. Empty citation (help) 
  5. Uhakheme, Ozolua (25 January 2016). "Nigerian author wins Premio Ostana award for scriptures". The Nation. 
  6. "Giunge a conclusione l'ottava edizione del Premio Ostana". Retrieved 2016-06-06.