Konstantínos Alexandrou Karamanlís (ojoibi September 14, 1956) je oloselu omo ile Griisi ati Alakoso Agba ile Griisi lati 10 March 2004 titi de 5 October, 2009.

Kóstas Alexándrou Karamanlís
Κωνσταντίνος Αλεξάνδρου Καραμανλής

Alakoso Agba ile Griisi
In office
10 March, 2004 – 5 October, 2009
ÀàrẹKarolos Papoulias
AsíwájúCostas Simitis
Arọ́pòGeorge Papandreou
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹ̀sán 1956 (1956-09-14) (ọmọ ọdún 68)
Country flag Athens, Greece
Ẹgbẹ́ olóṣèlúND
(Àwọn) olólùfẹ́Natasa Pazaïti
ResidenceMaximos Mansion, Athens (official)