Kudirat Abíọ́lá

(Àtúnjúwe láti Kudirat Abiola)

Kúdíràtù Abíọ̀lá (ọjọ́ ìbí: Kudirat Olayinka Adeyemi) tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kẹfà ọdún 1951 (1951 - 4 June, 1996)[1][2] jẹ́ òṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Ó tún jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó M. K. O. Abíọ́lá.

Kudirat Abíọ́lá
Kudirat.gif
ItokasiÀtúnṣe