Kukere
"Kukere" (nínú èdè Efik: "má ronú") jẹ́ orin láti ọwọ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Iyanya.[2] Orin náà jáde gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn orin nínú àwo-orin Desire (2013). Lẹ́yìn tí wọ́n gbé orin náà jáde, orin náà wọ ipò kìíní nínú àtẹ Top FM ti oṣù Karùn-ún, Soundcity Viewers Choice, Rhythm FM, àtiThe Beat 99.9 FM Blackberry. Àmọ́ ipò kejì lo wà lórí àtẹ Radio Port Harcourt.[3] "Kukuere" gba àmì-ẹ̀yẹ Hottest Single of the Year ní Nigeria Entertainment Awards ti ọdún 2013, àti Best Pop Single ní The Headies ti ọdún 2012.
"Kukere" | ||||
---|---|---|---|---|
Fáìlì:Iyanya - Kukere cover.jpg | ||||
Single by Ìyanya | ||||
from the album Desire | ||||
Released | 4 December 2011[1] | |||
Recorded | 2010–11 | |||
Genre | Afrobeats | |||
Length | Àdàkọ:Duration | |||
Label | Made Men Music Group | |||
Songwriter(s) | Iyanya Mbuk, Dapo Daniel Oyebanjo | |||
Producer(s) | D'Tunes | |||
Ìyanya singles chronology | ||||
| ||||
Àdàkọ:External music video |
Ìpìlẹ̀
àtúnṣeÀwọn oníjó CEO farahàn níbi ìṣeré orin náà ní Britain's Got Talent.[4] Cokobar àti Iyanya ṣètò ìdíje Kukere Queen láti lè ṣe ìgbélárugẹ orin náà ní ìlú London. Ìdíje náà gba àwọn olùdíje láàyè láti fi fídíò ijó wọn ránṣẹ́, àti ìdí mẹ́ta tí ó yẹ fún olùdíje náà láti gbégbá orókè.[5]
Ìgbóríyìn fún
àtúnṣeỌdún | Ayẹyẹ ìgba àmì-ẹ̀yẹ | Àpejúwe àmì-ẹ̀yẹ | Èsì | Ref |
---|---|---|---|---|
2013 | Nigeria Entertainment Awards | Hottest Single of the Year | Gbàá | [6] |
City People Entertainment Awards | Most Popular Song of the Year | Wọ́n pèé | [7] | |
2012 | Nigeria Music Video Awards (NMVA) | Best Contemporary Afro (Live Beats choice) | Wọ́n pèé | [8] |
The Headies 2012 | Best Pop Single | Gbàá | [9][10] | |
Song of the Year | Wọ́n pèé |
Kukere (Àtúnkọ)
àtúnṣe"Kukere (Remix)" | ||||
---|---|---|---|---|
Fáìlì:Iyanya's Kukere Remix cover.jpg | ||||
Single by Iyanya featuring D'banj | ||||
from the album Desire | ||||
Released | 20 Oṣù Kẹjọ 2012 | |||
Recorded | 2012 | |||
Genre | Afrobeats | |||
Length | Àdàkọ:Duration | |||
Label | Made Men Music Group | |||
Songwriter(s) | Iyanya Mbuk, Dapo Daniel Oyebanjo | |||
Producer(s) | D'Tunes | |||
Iyanya singles chronology | ||||
|
Àtúnkọ orin "Kukere" jáde ní ọjọ́ ogun oṣù Kẹjọ ọdún 2012; ohun D'banj sì ni ó hàn jù nínú orin náà.[11] Àtúnkọ yìí ní àkóónú bí i ti àkọ́kọ́ tó jáde, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ohun èlò orin tó wà nínú orin àkọ́kọ́ farahàn nínú àtúnkọ yìí.[12]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "New Heat: Iyanya – Kukere". 360nobs. Retrieved 6 October 2013.
- ↑ Olonilua, Ademola (2023-04-19). "Iyanya: Why I'm scared of marriage". Daily Trust. Retrieved 2024-12-13.
- ↑ "Iyanya Mbuk Biography (Nigerian Music Artist)". Nigerian Music Network. Archived from the original on 18 August 2013. Retrieved 3 August 2013.
- ↑ "Booty-tastic! CEO Dancers shake the BGT stage – With Iyanya (Kukere) & D' banj (Oliver)". sndmag. Archived from the original on 21 September 2013. Retrieved 3 August 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Iyanya Picks his Kukere Queen! Co-Hosts "Kukere Concert" With Tonto Dikeh on 9th June 2013 in London". Bella Niaja. Retrieved 3 August 2013.
- ↑ "Full List Of Nigeria Entertainment Awards Winners". spyghana. Retrieved 4 September 2013.
- ↑ Aiki, Damilare (19 June 2013). "Ice Prince, Omotola Jalade-Ekeinde, Sarkodie, Nse Ikpe-Etim, Yvonne Okoro, Tonto Dikeh & BellaNaija Nominated for the 2013 City People Entertainment Awards - See the Full List". Bellanaija. Retrieved 19 December 2013.
- ↑ "Nigerian Music Video Awards (NMVA 2012 ) Full Winners List". Tooxclusive. Retrieved 24 October 2013.
- ↑ "Headies Awards 2012: Full List Of Winners". ModernGhana. Retrieved 30 July 2013.
- ↑ "The Headies (Hip Hop World Awards 2012) Winners List". Hiphopworldmagazine. Archived from the original on 29 October 2013. Retrieved 13 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Premiere: Iyanya-Kukere Remix ft D'banj". Gidilounge. Archived from the original on 10 June 2015. Retrieved 8 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Iyanya – Kukere (Remix) (Feat. D'Banj)". BiGx Media Company. Archived from the original on 8 December 2013. Retrieved 8 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)