Kuru jẹ́ ìlú tó wà ní JosIpinle Plateau ní apá gúúsù orílẹ́-èdè Nàìjíríà. Ogún máìlì ló wà láàárí ìlú Jos àti Kuru. Àpapọ̀ ìlú kéréje, abúlé, àti agboolé tí ò jìnà síra ni ó wà ní Kuru.

Kuru pín sí méjì, Kuru A àti Kuru B, àpapọ̀ àwọn ìlú bíi; Danchol, Dakan, Dazek, Gwes, Hwak, Kushe, Vwei àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní ó bí Kuru. Ìdàgbàsókè ayé òde-òní ni ó bí National Institute for Policy and Strategic Studies, Kuru ní ẹ̀bádò Vom. Àmọ́, wọ́n yan ìlú Kuru láti fi sọ ilé-ìwé yìí.

Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ àtúnṣe

Kuru ní ilé-ìwé girama tí a mọ̀ sí Government science School, http://www.gsskuru.com Archived 2022-05-29 at the Wayback Machine.. Òun sì ni olùgbàlejò ilé-ìwé National Institute for Policy and Strategic Studies, Kuru tí àwọn èèyàn jàǹkànjàǹkàn, olóṣèlú nílẹ̀ yìí àti lókè òkun.

Àwọn èèyàn àtúnṣe

Ọ̀pọ̀ àwọn olùgbé ìlú Kuru pọ̀ jù sí ìlú Berom, iye àwọn ará-ìlú Kuru á máa lọ bíi 4,331.

Lílọ bíbọ̀ àtúnṣe

Ìlú Kuru wà láàárín Nigerian Railway Corporation tí ó so ìlú Port Harcourt, Enugu, Kafancha, Kuru, Bauchi àti Maiduguri.[1]

Ọdún 1838 ni wọ́n dá ìlú Kuru sílẹ̀. Ọdún 2004 ni wọ́n ṣe ojú-ọ̀nà reluwé àkọ́kọ́ sí ìlú náà. When the first railway that was designed in 1943 was built there in 2004.

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. ""NigeriaFirst.org: Revamping the Nigerian Railway"". Archived from the original on 2006-12-16. Retrieved 2007-04-06.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)