Lérè Pàímọ́
Lérè Pàímọ́, OFR (tí wọ́n bí ní oṣù kọkànlá ọdún 1939) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ògbómọ̀ṣọ́, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2][3]
Lere Paimo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ogbomosho, Oyo State, Nigeria | 19 Oṣù Kọkànlá 1939
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Eda Onile Ola |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1960–present |
Awards | MFR |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "People call me from everywhere to consult oracle for them –Lere Paimo". punchng.com. Archived from the original on 2015-02-08. Retrieved 2015-02-18.
- ↑ "Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today. 2015-09-30. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ Adekunle, Jimoh Taofik (2019-11-20). "Ogbomosho: Elemosho, Soun and Crux of History". Republican Newspaper. Archived from the original on 2019-12-17. Retrieved 2019-12-17.