Lawrence Douglas "Doug" Wilder (Ọjọ́ kẹtàdínlogún Oṣù kínín Ọdún 1931) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà, ọmọ Afíríka-Amẹ́ríkà àkókó tí wọ́n dìbò yàn gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ìpílẹ̀ Virginia, àti ẹnìkejì tó di gómìnà ìpínlè ní Amẹ́ríkà.[1][2]

Lawrence Douglas Wilder
Douglas Wilder 2003 NIH.jpg
78th Mayor of Richmond, Virginia
In office
2005–2009
AsíwájúRudolph McCollum Jr.
Arọ́pòDwight Clinton Jones
66th Governor of Virginia
In office
January 14, 1990 – January 15, 1994
LieutenantDon Beyer
AsíwájúGerald L. Baliles
Arọ́pòGeorge F. Allen
35th Lieutenant Governor of Virginia
In office
January 18, 1986 – January 14, 1990
GómìnàGerald L. Baliles
AsíwájúDick Davis
Arọ́pòDon Beyer
Member of the Senate of Virginia
In office
1969–1985
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 17, 1931 (1931-01-17) (ọmọ ọdún 89)
Richmond, Virginia
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
Other political
affiliations
Independent
(Àwọn) olólùfẹ́Eunice Montgomery (div.)
Alma materVirginia Union University
Howard University
AwardsBronze Star Medal
Military service
Battles/warsKorean War

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe