Labrador je agbegbe lariwa oto ninu igberiko Newfoundland àti Labrador ti orile-ede Kánádà. O ni apa to wa lorile igberiko yi, to je yiyasoto lodo erekusu Newfoundland pelu Strait of Belle Isle.

Maapu LabradorItokasiÀtúnṣe