Newfoundland àti Labrador
Newfoundland àti Labrador (pronounced /njuːfəndˈlænd ənd læbrəˈdɔr/; Faransé: Terre-Neuve-et-Labrador, Irish: Talamh an Éisc agus Labradar, Látìnì: Terra Nova) je igberiko kan ti orile-ede Kanada ni eti Atlantiki orile-ede yi ni apaariwailaorun Ariwa Amerika. Igberiko yi ja si apa meji: erekusu Newfoundland lookan etiodo apailaorun, ati Labrador to wa lorile ni ariwaiwoorun erekusu eyun.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |